Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 15:46 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jóṣẹ́fù sì ti ra aṣọ ọ̀gbọ̀ wá. Ó sọ òkú Jésù kalẹ̀: ó sì fi aṣọ ọ̀gbọ̀ náà dì í. Ó sì tẹ́ ẹ sí inú ibojì, tí wọ́n gbẹ́ sí ara àpáta. Ó wá yí òkúta dí ẹnu ibojì náà.

Ka pipe ipin Máàkù 15

Wo Máàkù 15:46 ni o tọ