Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 14:65 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn kan sì bẹ̀rẹ̀ sí í tu itọ̀ sí i lára. Wọ́n dì í lójú. Wọ́n ń gbà a lẹ́ṣẹ̀ẹ́ lójú. Wọ́n fi ṣe ẹlẹ́yà pé, “Sọtẹ́lẹ̀!” Àwọn olùsọ́ sì ń fi àtẹ́lẹwọ́ wọn gbá a lójú.

Ka pipe ipin Máàkù 14

Wo Máàkù 14:65 ni o tọ