Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 14:64 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ̀yin fúnra yín ti gbọ́ ọ̀rọ̀ òdì tí ó sọ. Kí ni ẹ rò pé ó tọ́ kí a ṣe?”Gbogbo wọ́n sì dáhùn wí pé, “Ó jẹ̀bi ìkú.”

Ka pipe ipin Máàkù 14

Wo Máàkù 14:64 ni o tọ