Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 13:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ṣùgbọ́n ni ọjọ́ wọ̀nyí lẹ́yìn ìpọ́njú tí mo sọ yìí,“ ‘òòrùn yóò sókùnkùn,òṣùpá kò ní tan ìmọ́lẹ̀ rẹ̀.

Ka pipe ipin Máàkù 13

Wo Máàkù 13:24 ni o tọ