Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 13:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ẹni ti ń bẹ lórí ilé má ṣe sọkalẹ̀ lọ sínú ilé, bẹ́ẹ̀ ni kí ó má si ṣe wọ inú rẹ̀, láti mú ohunkóhun jáde nínú ilé rẹ̀.

Ka pipe ipin Máàkù 13

Wo Máàkù 13:15 ni o tọ