Àwọn ènìyàn yóò kórira yín nítorí tí ẹ jẹ́ tèmi. Ṣùgbọ́n ẹni tó bá fara da ìyà títí dé òpin tí kò sì kọ̀ mí sílẹ̀ òun ni yóò rí ìgbàlà.