Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 12:41 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù jókòó kọjú sí àpótí ìṣúra: ó ń wo ìjọ ènìyàn ti ń sọ owó sínú àpótí ìṣúra, ọ̀pọ̀ àwọn ọlọ́rọ̀ sì sọ púpọ̀ sí i.

Ka pipe ipin Máàkù 12

Wo Máàkù 12:41 ni o tọ