Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 11:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí wọ́n ti ń tú u, díẹ̀ nínú àwọn tí ó dúró níbẹ̀ bi wọ́n léèrè pé, “Kí ni ẹ̀ ń ṣe, È ń tú ọmọ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́?”

Ka pipe ipin Máàkù 11

Wo Máàkù 11:5 ni o tọ