Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 11:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ọmọ-ẹ̀yìn méjì náà lọ bí ó ti rán wọn. Wọ́n rí ọmọ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ tí ó dúró ní ìta gbangba tí a so mọ́lẹ̀.

Ka pipe ipin Máàkù 11

Wo Máàkù 11:4 ni o tọ