Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 10:5-7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

5. Ṣùgbọ́n Jésù dá wọn lóhùn, ó sì wí pé, “Mósè kọ òfin yìí fun un yín nítorí ẹ jẹ́ ọlọ́kàn líle.

6. Ṣùgbọ́n láti ìgbà tí ayé ti ṣẹ̀, Ọlọ́run dá wọn ní akọ àti abo.

7. Nítorí ìdí èyí, ọkùnrin yóò fi baba àti ìyá rẹ̀ sílẹ̀ yóò sì faramọ́ aya rẹ̀.

Ka pipe ipin Máàkù 10