Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 10:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n dáhùn pé, “Mósè yọ̀ǹda ìkọ̀sílẹ̀. Ohun tí ọkùnrin náà yóò ṣe ni kí ó fún un ní ìwé ìkọ̀sílẹ̀, lẹ́yìn èyí, ààyè wà láti kọ obìnrin náà sílẹ̀.”

Ka pipe ipin Máàkù 10

Wo Máàkù 10:4 ni o tọ