Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 10:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù wò ó bí ọkùnrin náà ti ń lọ. Ó yípadà, ó sì sọ fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ pé, “Àní, ohun ìṣòro ni fún ọlọ́rọ̀ láti wọ ìjọba Ọlọ́run!”

Ka pipe ipin Máàkù 10

Wo Máàkù 10:23 ni o tọ