Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Máàkù 10:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí ọkùnrin yìí gbọ́ èyí, ojú rẹ̀ korò, ó sì lọ pẹ̀lú ìbànújẹ́, nítorí pé ó ní ọrọ̀ púpọ̀.

Ka pipe ipin Máàkù 10

Wo Máàkù 10:22 ni o tọ