Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 8:51 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n nígbà tí Jésù sì wọ ilé, kò jẹ́ kí ẹnikẹ́ni wọlé, bí kò ṣe Pétérù, àti Jákọ́bù, àti Jòhánù, àti baba àti ìyá ọmọbìnrin náà.

Ka pipe ipin Lúùkù 8

Wo Lúùkù 8:51 ni o tọ