Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 6:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ó ti wọ ilé Ọlọ́run lọ, tí ó sì mú àkàrà ìfihàn tí ó sì jẹ ẹ́, tí ó sì fi fún àwọn tí ń bẹ lọ́dọ̀ rẹ̀ pẹ̀lú; tí kò yẹ fún un láti jẹ, bí kò ṣe fún àwọn àlùfáà níkan ṣoṣo?”

Ka pipe ipin Lúùkù 6

Wo Lúùkù 6:4 ni o tọ