Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 6:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù sì dá wọn lóhùn pé, “Ẹ̀yin kò kà nípa ohun tí Dáfídì ṣe, nígbà tí ebi ń pa òun tìkárarẹ̀ àti àwọn tí ó wà lọ́dọ̀ rẹ̀;

Ka pipe ipin Lúùkù 6

Wo Lúùkù 6:3 ni o tọ