Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 5:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sáà sì kíyèsí i, àwọn Ọkùnrin kan gbé ẹnikantí ó ní àrùn egba wà lórí àketè: wọ́n ń wá ọ̀nà àti gbé e wọlé, àti láti tẹ́ ẹ ṣíwájú Jésù.

Ka pipe ipin Lúùkù 5

Wo Lúùkù 5:18 ni o tọ