Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 5:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ijọ́ kan, bí ó sì ti ń kọ́ni, àwọn Farisí àti àwọn amòfin jókòó pẹ̀lú rẹ̀, àwọn tí ó ti àwọn ìletò Gálílì gbogbo, àti Jùdíà, àti Jerúsálémù wá: agbára Olúwa sì ń bẹ pẹ̀lú rẹ̀ láti mú wọn láradá.

Ka pipe ipin Lúùkù 5

Wo Lúùkù 5:17 ni o tọ