Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 24:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì ṣe, bí ó ti bá wọn jókòó ti oúnjẹ, ó mú àkàrà, ó súre sí i, ó sì bù ú, ó sì fifún wọn.

Ka pipe ipin Lúùkù 24

Wo Lúùkù 24:30 ni o tọ