Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 24:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì bi wọ́n pé, “Kí ni?”Wọ́n sì wí fún un pé, “Ní ti Jésù ti Násárẹ́tì, ẹni tí ó jẹ́ wòlíì, tí ó pọ̀ ní ìṣe àti ní ọrọ̀ níwájú Ọlọ́run àti gbogbo ènìyàn,

Ka pipe ipin Lúùkù 24

Wo Lúùkù 24:19 ni o tọ