Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 23:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì dá ẹni tí wọ́n fẹ́ sílẹ̀ fún wọn, ẹni tí a tìtorí ọ̀tẹ̀ àti ìpànìyàn sọ sínú túbú; ṣùgbọ́n ó fi Jésù lé wọn lọ́wọ́.

Ka pipe ipin Lúùkù 23

Wo Lúùkù 23:25 ni o tọ