Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 23:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Gbogbo ìjọ ènìyàn sì dìde, wọ́n sì fà á lọ sí ọ̀dọ̀ Pílátù.

2. Wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí fi ẹ̀sùn kàn án, wí pé, “Àwa rí ọkùnrin yìí ó ń yí orílẹ̀-èdè wa lọ́kàn padà, ó sì ń dá wọn lẹ́kun láti san owó-òde fún Késárì, ó ń wí pé, òun tìkara-òun ni Kírísítì ọba.”

Ka pipe ipin Lúùkù 23