Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 20:46 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ẹ máa kíyèsára lọ́dọ̀ àwọn akọ̀wé, tí wọ́n fẹ́ láti máa rìn ní aṣọ gígùn, tí wọ́n sì fẹ́ ìkíni ní ọjà, àti ibùjókòó ọlá nínú sínágọ́gù, àti ipò ọlá ní ibi àsè;

Ka pipe ipin Lúùkù 20

Wo Lúùkù 20:46 ni o tọ