Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 20:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n sì bí i, pé, “Olùkọ́ àwa mọ̀ pé, ìwọ a máa sọ̀rọ̀ fún ni, ìwọ a sì máa kọ́ni bí ó ti tọ́, bẹ́ẹ̀ ni ìwọ kì í ṣojúsájú ẹnìkan ṣùgbọ́n ìwọ ń kọ́ni ní ọ̀nà Ọlọ́run lótítọ́.

Ka pipe ipin Lúùkù 20

Wo Lúùkù 20:21 ni o tọ