Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 15:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì dáhùn ó wí fún bàbá rẹ̀ pé, ‘Wòó, láti ọdún mélòó wọ̀nyí ni èmi ti ń sìn ọ́, èmi kò sì rú òfin rẹ rí: ìwọ kò sì tí ì fi ọmọ ewúrẹ́ kan fún mi, láti fi bá àwọn ọ̀rẹ́ mi ṣe àríyá:

Ka pipe ipin Lúùkù 15

Wo Lúùkù 15:29 ni o tọ