Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 15:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì dìde, ó sì tọ baba rẹ̀ lọ.“Ṣùgbọ́n nígbà tí ó sì wà ní òkèrè, baba rẹ̀ rí i, àánú ṣe é, ó sì súré, ó rọ̀ mọ́ ọn ní ọrùn, ó sì fi ẹnu kò ó ní ẹnu.

Ka pipe ipin Lúùkù 15

Wo Lúùkù 15:20 ni o tọ