Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 15:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Kò sì tó ọjọ́ mélòó kan lẹ́yìn náà, èyí àbúrò kó ohun gbogbo tí ó ní jọ, ó sì mú ọ̀nà àjò rẹ̀ pọ̀n lọ sí ilẹ̀ òkèrè, níbẹ̀ ni ó sì gbé fi ìwà wọ̀bìà ná ohun ìní rẹ̀ ní ìnákúnàá.

Ka pipe ipin Lúùkù 15

Wo Lúùkù 15:13 ni o tọ