Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 12:54-57 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

54. Ó sì wí fún ìjọ ènìyàn pẹ̀lú pé, “Nígbà tí ẹ̀yin bá rí ìkùukù àwọ̀sánmà tí ó ṣú ní ìhà ìwọ̀ oòrùn, lọ́gán ni ẹ̀yin yóò sọ pé, ‘Ọ̀wàrà òjò ń bọ̀,’ a sì rí bẹ́ẹ̀.

55. Nígbà tí afẹ́fẹ́ gúsù bá ń fẹ́, ẹ̀yin á ní, ‘Oòrùn yóò mú,’ yóò sì ṣe bẹ́ẹ̀.

56. Ẹ̀yin àgàbàgebè! Ẹ̀yin le mòye ojú ọ̀run àti ti ayé. Èé ha ti ṣe tí ẹ̀yin kò mọ àkókò yìí?

57. “Èé ha ti ṣe tí ẹ̀yin tìkárayín kò fi ro ohun tí ó tọ́?

Ka pipe ipin Lúùkù 12