Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 12:53 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A ó ya baba nípa sí ọmọ rẹ̀ ọkùnrin, àti ọmọ ọkùnrin sí baba; ìyá sí ọmọbìnrin, àti ọmọbìnrin sí ìyá rẹ̀, ìyá ọkọ sí ìyàwó ọmọ, àti ìyàwó ọmọ sí ìyá ọkọ rẹ̀.”

Ka pipe ipin Lúùkù 12

Wo Lúùkù 12:53 ni o tọ