Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 10:40 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n Mátà ń ṣe ìyọnu ohun púpọ̀, ó sì tọ̀ ọ́ wá, ó wí pé, “Olúwa, ìwọ kò sì bìkítà sí ti arábìnrin mi pé ó fi mí sílẹ̀ láti máa nìkàn ṣe ìránṣẹ́? Wí fún un kí ó ràn mí lọ́wọ́.”

Ka pipe ipin Lúùkù 10

Wo Lúùkù 10:40 ni o tọ