Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 10:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì tọ̀ ọ́ lọ, ó sì di ọgbẹ́ rẹ̀, ó da òróró àti ọtí wáìnì sí i, ó sì gbé e lé orí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ ti òun tìkalárarẹ̀, ó sì mú un wá sí ilé èrò, a sì ń ṣe ìtọ́jú rẹ̀.

Ka pipe ipin Lúùkù 10

Wo Lúùkù 10:34 ni o tọ