Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lúùkù 10:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

‘Eruku ìlú yín tí ó kù sí wa lẹ́sẹ̀, a gbọ̀n ọ́n sílẹ̀ fún yín! Ṣùgbọ́n ẹ mọ èyí pé, ìjọba Ọlọ́run kù dẹ̀dẹ̀ sí yín!’

Ka pipe ipin Lúùkù 10

Wo Lúùkù 10:11 ni o tọ