Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kólósè 3:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ohunkóhun tí ẹ̀yín bá sì ń ṣe ní ọ̀rọ̀ tàbí ní ìṣe, ẹ máa ṣe gbogbo wọn ní orúkọ Jésù Olúwa, ẹ máa fi ọpẹ́ fún Ọlọ́run baba nípasẹ̀ rẹ̀.

Ka pipe ipin Kólósè 3

Wo Kólósè 3:17 ni o tọ