Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 9:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó dáhùn ó sì wí fún un pé, “Ọkùnrin kan tí a ń pè ní Jésù ni ó ṣe amọ̀, ó sì fi kùn mí lójú, ó sì wí fún mi pé, ‘Lọ sí adágún Sílóámù, kí o sì wẹ̀,’ èmi sì lọ, mo wẹ̀, mo sì ríran.”

Ka pipe ipin Jòhánù 9

Wo Jòhánù 9:11 ni o tọ