Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 8:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù sì tún sọ fún wọn pé, “Èmi ni ìmọ́lẹ̀ ayé, ẹni tí ó bá tọ̀ mí lẹ́yìn kì yóò rìn nínú òkùnkùn, ṣùgbọ́n yóò ní ìmọ́lẹ̀ ìyè.”

Ka pipe ipin Jòhánù 8

Wo Jòhánù 8:12 ni o tọ