Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 6:69-71 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

69. Àwa sì ti gbàgbọ́, a sì mọ̀ pé ìwọ ni Kristì náà, Ọmọ Ọlọ́run alààyè.”

70. Jésù dá wọn lóhùn pé, “Ẹ̀yin méjìlá kọ́ ni mo yàn, ọ̀kan nínú yín kò ha sì ya Èṣù?”

71. (Ó ń sọ ti Júdásì Iskariótù Ọmọ Símónì ọ̀kan nínú àwọn méjìlá: nítorí pé òun ni ẹni tí yóò fi í hàn.)

Ka pipe ipin Jòhánù 6