Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 6:68 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni Símónì Pétérù dá a lóhùn pé, “Olúwa, ọ̀dọ̀ ta ni àwa ó lọ? Ìwọ ni ó ni ọ̀rọ̀ ìyè àìnípẹ̀kun.

Ka pipe ipin Jòhánù 6

Wo Jòhánù 6:68 ni o tọ