Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 21:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọ̀rọ̀ yìí sì tàn ká láàrin àwọn arákùnrin pé, ọmọ-ẹ̀yìn náà kì yóò kú: ṣùgbọ́n Jésù kò wí fún un pé, Òun kì yóò kú; ṣùgbọ́n, “Bí èmi bá fẹ́ kí ó dúró títí èmi ó fi dé, kínni èyí jẹ́ sí ọ?”

Ka pipe ipin Jòhánù 21

Wo Jòhánù 21:23 ni o tọ