Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 21:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù wí fún un pé, “Bí èmi bá fẹ́ kí ó dúró títí èmi ó fi dé, kínni èyí jẹ́ sí ọ? Ìwọ máa tọ̀ mí lẹ́yìn.”

Ka pipe ipin Jòhánù 21

Wo Jòhánù 21:22 ni o tọ