Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 21:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pétérù sì yípadà, ó rí ọmọ-ẹ̀yìn náà, ẹni tí Jésù fẹ́ràn, ń bọ̀ lẹ́yìn; ẹni tí ó fararọ̀ súnmọ́ àyà rẹ̀ nígbà oúnjẹ alẹ́ tí ó sì wí fún un pé, “Olúwa, ta ni ẹ̀ni tí ó fi ọ́ hàn?”

Ka pipe ipin Jòhánù 21

Wo Jòhánù 21:20 ni o tọ