Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 21:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó wí fún un nígbà kẹ́ta pé, “Símónì, ọmọ Jónà, ìwọ fẹ́ràn mi bí?”Inú Pétérù sì bàjẹ́, nítorí tí ó wí fún un nígbà ẹ̀kẹ́ta pé, “Ìwọ fẹ́ràn mi bí?” Ó sì wí fún un pé, “Olúwa, ìwọ mọ ohun gbogbo; ìwọ mọ̀ pé, mo fẹ́ràn rẹ.”Jésù wí fún un pé, “Máa bọ́ àwọn àgùntàn mi.”

Ka pipe ipin Jòhánù 21

Wo Jòhánù 21:17 ni o tọ