Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 21:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó tún wí fún un nígbà kejì pé, “Símónì ọmọ Jónà, ìwọ fẹ́ mi bí?”Ó wí fún un pé, “Bẹ́ẹ̀ ni Olúwa; ìwọ mọ̀ pé, mo fẹ́ràn rẹ.”Ó wí fún un pé, “Máa bọ́ àwọn àgùntàn mi.”

Ka pipe ipin Jòhánù 21

Wo Jòhánù 21:16 ni o tọ