Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 15:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kì í ṣe ẹ̀yin ni ó yàn mí, ṣùgbọ́n èmi ni ó yàn yín, mo sì fi yín sípò, kí ẹ̀yin kí ó lè lọ, kí ẹ sì so èso, àti kí èṣo yín lè dúró; kí ohunkóhun tí ẹ bá bèrè lọ́wọ́ Baba ní orúkọ mi, kí ó lè fi í fún yín.

Ka pipe ipin Jòhánù 15

Wo Jòhánù 15:16 ni o tọ