Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 15:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi kò pè yín ní ọmọ ọ̀dọ̀ mọ́; nítorí ọmọ ọ̀dọ̀ kò mọ ohun tí olúwa rẹ̀ ń ṣe: ṣùgbọ́n èmi pè yín ní ọ̀rẹ́ nítorí ohun gbogbo tí mo ti gbọ́ láti ọ̀dọ̀ Baba mi wá, mo ti fi hàn fún yín.

Ka pipe ipin Jòhánù 15

Wo Jòhánù 15:15 ni o tọ