Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 11:55 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àjọ ìrékọjá àwọn Júù sì sún mọ́ etílé: ọ̀pọ̀lọpọ̀ láti ìgbéríko sì gòkè lọ sí Jérúsálẹ́mù ṣáájú ìrékọjá, láti ya ara wọn sí mímọ́.

Ka pipe ipin Jòhánù 11

Wo Jòhánù 11:55 ni o tọ