Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 11:39 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù wí pé, “Ẹ gbé òkúta náà kúrò!”Màtá, arábìnrin ẹni tí ó kú náà wí fún un pé, “Olúwa, ó ti ń rùn nísinsin yìí: nítorí pé ó di ijọ́ kẹrin tí ó tí kú.”

Ka pipe ipin Jòhánù 11

Wo Jòhánù 11:39 ni o tọ