Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jòhánù 11:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí ó sì ti wí èyí tan, ó lọ, ó sì pe Màríà arábìnrin rẹ̀ sẹ́yìn wí pé, “Olùkọ́ dé, ó sì ń pè ọ́.”

Ka pipe ipin Jòhánù 11

Wo Jòhánù 11:28 ni o tọ