Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jákọ́bù 5:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ènìyàn onírúurú ìwà bí àwa ni Èlíjà, ó gbàdúrà gidigidi pé kí òjò kí ó má ṣe rọ̀, òjò kò sì rọ̀ sórí ilẹ̀ fún ọdún mẹ́ta òun oṣù mẹ́fà.

Ka pipe ipin Jákọ́bù 5

Wo Jákọ́bù 5:17 ni o tọ