Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jákọ́bù 5:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ jẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ yín fún ara yín, kí ẹ sì máa gbàdúrà fún ara yín, kí a lè mú yín láradá. Iṣẹ́ tí àdúrà olódodo ń se ní agbára púpọ̀.

Ka pipe ipin Jákọ́bù 5

Wo Jákọ́bù 5:16 ni o tọ