Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìfihàn 7:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo sì wí fún un pé, “Olúwa mi, ìwọ ni o lè mọ̀.”Ó sì wí fún mí pé, “Àwọn wọ̀nyí ni o jáde láti inú ìpọ́njú ńlá, wọ́n sì fọ aṣọ wọ́n sì sọ wọ́n di funfun nínú Ẹ̀jẹ̀ Ọ̀dọ́-Àgùntàn náà.

Ka pipe ipin Ìfihàn 7

Wo Ìfihàn 7:14 ni o tọ